Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,162,024 members, 7,849,129 topics. Date: Monday, 03 June 2024 at 02:59 PM

N Je Omo Olohun Ni Jesu? (apa Kini) - Religion - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Religion / N Je Omo Olohun Ni Jesu? (apa Kini) (2708 Views)

Belief In God Is A Mental Illness by APA / The Life And Times Of 'Jesu Oyingbo' (Jesus Of Oyingbo) / Need Lyrics On : Alade Ogo, Jesu Logbara And Talo Dabere Songs (2) (3) (4)

(1) (Reply) (Go Down)

N Je Omo Olohun Ni Jesu? (apa Kini) by OPEYEMIAD(m): 6:19pm On Sep 07, 2012
i just saw this from one website and decided to share
Iwonyii ni IFOROWERO laarin MUSULUMI ati PASITO lori, Oro Igbala. E maa ba wa kalo:

PASITO:- E kaaro, n je e le gbawa laaye lati bayin soro Olohun?
MUSULUMI: Beeni, ni igba ti o je wi pe gbogbo wa la n wa igbala si iye ainipekun (ogba idera) ti a mo si Paradise, anfaani wa fun yin lati ba wa soro Olohun, Nitori naa, Pasito, e tesiwaju ninu ibani soro yin.
PASITO:- E seun, Olohun yoo tubo maa so agbara yin di otun. MUSULUMI:- Aamin . PASITO:- N je e gba lotito ati lododo wi pe omo Olohun ni Jesu n se?

MUSULUMI:- Rara o, awa musulumi ko gba bee, nitori pe, Olohun so fun wa ninu Alukurani wi pe, oun ko bimo bee sini, enikan ko bi oun. Olohun tun je ki awa Musulumi mo ninu Alukurani, Suratul-Taobat, ori kesan, ese ogbon wi pe; “Awon Yahudi ni omo Olohun ni Usairu; awon Kristieni naa si n wi pe, omo Olohun ni Al-Masihu (Jesu). Iwonyii ni oro buruku ti o n jade lenu won. Won n fi ara we oro awon ti o se aigbagbo ni isaaju. Olohun gegun fun won. E woo bi won ti seri kuro nibi otito “ (Alukurani, 9:30) Olohun ni oro buruku ni lati maa so wi pe oun bimo. Bakan naa, Olohun tun tesiwaju ninu Alukurani Suratul-Mariyam, ori kokandinlogun, ese ikejidinlaadorun titi de iketaleelaadorun wi pe; “Ati pe, won n sope, (Oluwa) Ajoke aye fi enikan se omo. Dajudaju oro ti o buru ni won n so yii. Nitori oro yii, sanmo fe faya, ile si fe faya pelu, awon oke (apata) naa si fe wo ni wiwo patapata. Nitoripe, won n so pe Olorun bi omo kan. Ati pe, ko too fun (Oluwa) Ajoke aye pe ki o mu enikan ni omo. Ko si enikan ninu samon ati lori ile ayafi ki o wa ba (Oluwa) Ajoke aye ni jije Erusin: (Alukurani, 19:88-93) Nitori naa, Jesu kii se Omo Olohun. PASITO:- E se pupo, e jowo, e je ki a lo sinu Bibeli, ninu iwe Johannu, ori keta, ese kerindinlogun, eleyi ti o ka bayii wi pe; “Nitori Olohun fe araye to be gee ti o fi omo bibi re kan soso fun ni, ki enikeni ti o ba gbaa gbo, ma ba segbe, sugbon, ki o lee ni iye ainipekun “(Johanu, 3:16) . A o ri daju wi pe ninu ese Bibeli yii, Jesu je omo Olorun kan soso. Sugbon, ki lo de ti e fi n so pe, Jesu kii se omo Olohun, nigba ti, a kaa jade ninu Bibeli wi pe omo Olohun nii se. MUSULUMI:- E seun, mo fe ki e koko mo daju wi pe iforowero ti a n se yii wa ni ibamu si liana Bibeli, nitori pe, iwe Isaiah, ori kini, ese ikejidinlogun so pe; “Oluwa so wipe, wa nisinsinyii, ki e si je ki a so asoyepo {ISAIAH, 1:18] Bakan naa, a tun ri ka ninu iwe Tesalonika kinni, ori karun-un, ese ikokanlelogun wi pe; “E ma wadii ohun gbogbo daju, e di eyi ti o dara mu sinsin”
Nipa bayii, o se pataki fun gbogbo eda alaaye lati se iwadi finnifinni, ki a lee mo ododo yato si iro, ki a si di otito naa mu sinsinsin,
Re: N Je Omo Olohun Ni Jesu? (apa Kini) by OPEYEMIAD(m): 9:02pm On Sep 07, 2012
OPEYEMI AD: i just saw this from one website and decided to share

continue reading http://acadip.net/images/N%20JE%20OMO%20OLOHUN%20NI%20JESU.pdf
Re: N Je Omo Olohun Ni Jesu? (apa Kini) by OPEYEMIAD(m): 11:51pm On Sep 07, 2012
NOTE: WRITTEN WITH YORUBA LANGUAGE

1. ODODO FARAHAN http://acadip.net/images/ODODO%20FARAHAN.pdf

2. THE REVELATION http://acadip.net/images/THE%20REVELATION%20BOOK....pdf

more to come
Re: N Je Omo Olohun Ni Jesu? (apa Kini) by realBerni: 2:42pm On Sep 09, 2012
@OPEYEMI AD
MUSULUMI:- Rara o, awa musulumi ko gba bee, nitori pe, Olohun so fun wa ninu Alukurani wi pe, oun ko bimo bee sini, enikan ko bi oun. Olohun tun je ki awa Musulumi mo ninu Alukurani, Suratul-Taobat, ori kesan, ese ogbon wi pe; “Awon Yahudi ni omo Olohun ni Usairu; awon Kristieni naa si n wi pe, omo Olohun ni Al-Masihu (Jesu). Iwonyii ni oro buruku ti o n jade lenu won. Won n fi ara we oro awon ti o se aigbagbo ni isaaju. Olohun gegun fun won. E woo bi won ti seri kuro nibi otito “ (Alukurani, 9:30) Olohun ni oro buruku ni lati maa so wi pe oun bimo. Bakan naa, Olohun tun tesiwaju ninu Alukurani Suratul-Mariyam, ori kokandinlogun, ese ikejidinlaadorun titi de iketaleelaadorun wi pe; “Ati pe, won n sope, (Oluwa) Ajoke aye fi enikan se omo. Dajudaju oro ti o buru ni won n so yii. Nitori oro yii, sanmo fe faya, ile si fe faya pelu, awon oke (apata) naa si fe wo ni wiwo patapata. Nitoripe, won n so pe Olorun bi omo kan. Ati pe, ko too fun (Oluwa) Ajoke aye pe ki o mu enikan ni omo. Ko si enikan ninu samon ati lori ile ayafi ki o wa ba (Oluwa) Ajoke aye ni jije Erusin: (Alukurani, 19:88-93) Nitori naa, Jesu kii se Omo Olohun.

PASITO:- E se pupo, e jowo, e je ki a lo sinu Bibeli, ninu iwe Johannu, ori keta, ese kerindinlogun, eleyi ti o ka bayii wi pe; “Nitori Olohun fe araye to be gee ti o fi omo bibi re kan soso fun ni, ki enikeni ti o ba gbaa gbo, ma ba segbe, sugbon, ki o lee ni iye ainipekun “(Johanu, 3:16) . A o ri daju wi pe ninu ese Bibeli yii, Jesu je omo Olorun kan soso. Sugbon, ki lo de ti e fi n so pe, Jesu kii se omo Olohun, nigba ti, a kaa jade ninu Bibeli wi pe omo Olohun nii se.
MUSULUMI:- E seun, mo fe ki e koko mo daju wi pe iforowero ti a n se yii wa ni ibamu si liana Bibeli, nitori pe, iwe Isaiah, ori kini, ese ikejidinlogun so pe; “Oluwa so wipe, wa nisinsinyii, ki e si je ki a so asoyepo {ISAIAH, 1:18] Bakan naa, a tun ri ka ninu iwe Tesalonika kinni, ori karun-un, ese ikokanlelogun wi pe; “E ma wadii ohun gbogbo daju, e di eyi ti o dara mu sinsin”
Nipa bayii, o se pataki fun gbogbo eda alaaye lati se iwadi finnifinni, ki a lee mo ododo yato si iro, ki a si di otito naa mu sinsinsin,

SE ENIKAN GBODO BI EEYAN,KI OUN TO LE PE ENI NAA NI OMO OUN? A SAA RI ENI TI O JE WIPE KO BI OMO,SUGBON O NPE OMO ELOMIRAN NI OMO OUN, TI O SI NI IDI TI DARA LATI PEE NI OMO OUN, NITIRINAA,BOYA OLORUN BIMO,TABI KO BIMO, IYEN KO YE KI O JE ARIYANJIYAN RARA! JESU JE OMO OLORUN, KO DI DANDAN KI OLORUN BI JESU,SUGBON O LE PEE NI OMO OUN!

(1) (Reply)

Interrogating God - Douglas Anele / Against The Trinity / Redemption Camp; A Great Example Of Nigerian Hypocrisy In Religion

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 71
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.