Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,162,002 members, 7,849,036 topics. Date: Monday, 03 June 2024 at 01:43 PM

Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe - Forum Games (7) - Nairaland

Nairaland Forum / Entertainment / Forum Games / Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe (98300 Views)

Raiders! Vs Bears! L.i.v.e. / Colts Vs Jaguars L-ive / Your N.l First Crush - What Drew You To Him/her (2) (3) (4)

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) ... (25) (Reply) (Go Down)

Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by kolaoloye(m): 2:40pm On Oct 26, 2008
goodass:

o n ta mi, o n ro mi la n ko(r)la, . . . .
o n ta mi, o n ro mi la n ko(r)la, ti o ba jinna tan ni ndi oge. grin

@Godalone,
you can do better, try it again cheesy
Eniti ko ni jojo l'apa___________________
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by goodass(m): 8:22pm On Oct 26, 2008
kola oloye:

o n ta mi, o n ro mi la n ko(r)la, ti o ba jinna tan ni ndi oge. grin

@Godalone,
you can do better, try it again cheesy
Eniti ko ni jojo l'apa___________________
profesor JF Odunjo + DO Fagunwa combine!!!!! eyin gbona gan. a o le koyan yin kere nile yi.

eni ti ko ni jojo lapa kii ja ese (boxing) undecided

a kii shosha lodo. . . . . . .
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by Godalone(m): 2:11pm On Oct 27, 2008
[quote

a kii shosha lodo. . . . . . .
[quote][/quote]
Ki labelabe ma mo
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by goodass(m): 2:27pm On Oct 27, 2008
Godalone:

Ki labelabe ma mo

wel done, Godalone.

a kii moowe ([b]mor[/b]e+[b]we[/b]t). . . .
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by kolaoloye(m): 9:36am On Oct 28, 2008
Eniti ko ni jojo l'apa, kii dasa mo kio-kio grin

Olowo ki'je orogan,_______________________
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by Godalone(m): 12:40pm On Oct 28, 2008
Kola oloye omo agba ni he ni toto,wa de dagba wa tepa.
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by namun(f): 11:19pm On Oct 28, 2008
good job,
i wanna learn
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by dayokanu(m): 6:15am On Oct 30, 2008
Operekete n dagba ________________

Ogede dudu ko ya busan ________________
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by kolaoloye(m): 8:32am On Oct 30, 2008
dayokanu:

Operekete n dagba ________________

Ogede dudu ko ya busan ________________

Operekete n dagba ,inu Adamo nbaje
Ogede dudu ko ya busan, omo buruku ko ya lu'pa grin


Ina (flame) ti ko ba to'na _______________________________
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by Godalone(m): 8:33am On Oct 30, 2008
dayokanu:

Operekete n dagba ________________
Inu omo adamu nbaje.
dayokanu:

Ogede dudu ko ya busan ________________
Omo buruku ko se lupa.
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by mafolayomi(f): 5:16pm On Oct 30, 2008
Were dun wo
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by goodass(m): 5:36pm On Oct 30, 2008
mafolayomi:

Were dun wo

sugbon ko see bi lomo

kola oloye:

Operekete n dagba ,inu Adamo nbaje
Ogede dudu ko ya busan, omo buruku ko ya lu'pa grin


Ina (flame) ti ko ba to'na _______________________________

ni afopina n ba shere  undecided

goodass:


a kii moowe ([b]mor[/b]e+[b]we[/b]t). . . .

a kii moowe ([b]mor[/b]e+[b]we[/b]t). . . . . . .
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by kolaoloye(m): 4:13pm On Nov 03, 2008
@goodass,
O ko gba idahun si ibere yen grin Ti mo ba ti so fun e,mo ni lati fun e ni ibeere miran.Nje o faramo
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by goodass(m): 6:27pm On Nov 03, 2008
kola oloye:

@goodass,
O ko gba idahun si ibere yen grin Ti mo ba ti so fun e,mo ni lati fun e ni ibeere miran.Nje o faramo

bee ni mo fara moo. sugbon emi naa ko tii ri eni to dahun owe temi naa: a kii moowe (moowe=sabi swim). . . .
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by AkedeOba(m): 11:27pm On Nov 07, 2008
How much of Yoruba proverbs do you know ?
Do you know that you can create your own personal blog at www.yorubaland.org/community
Blog in Yoruba or English and share your stories and experiences to others worldwide

www.yorubaland.org/community
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by kolaoloye(m): 1:54pm On Nov 24, 2008
@goodass,
mo si nronu si ibeere re lowo cheesy sugbon eyi ni idahun si ibeere mi.
Ina ti ko ba to'na ni ito igbin le pa, ti ina ba to ina igbin a maa jona ti'karaun- ti'karaun grin
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by kolaoloye(m): 2:00pm On Nov 24, 2008
Eni ti o ba mo'ju ogun (god of iron)__________________________-
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by OLAADEGBU(m): 1:46am On Nov 28, 2008
kola oloye:

Eniti ko ni jojo l'apa, kii dasa mo kio-kio grin

Olowo ki'je orogan,_______________________

Olowo ki'je orogan, ki iwofa ma a je agun mate

---------------------

A nwona ati fi asiwere sile,_________________________________
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by kolaoloye(m): 8:25am On Nov 28, 2008
bro Ola,
E ma seun gaan ke cheesy. Awon owe kekeke yi ni awon omo Oodua ti gbagbe.
Mo npada bo lati wa dahun owe yin grin
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by OLAADEGBU(m): 6:27am On Nov 29, 2008
Arakunrin Kola omo awon agba,

Se alafia ni ewa. Eyin na a l'a nduro de ki e fun wa ni itumo awon owe yin ti o ni 'pon.
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by OLAADEGBU(m): 7:03pm On Dec 02, 2008
Arakunrin Kola, eti pe ju.

OLAADEGBU:

Olowo ki'je orogan, ki iwofa ma a je agun mate

---------------------

A nwona ati fi asiwere sile,_________________________________

A nwona ati fi asiwere sile, o ni bi a ba de oke odo ki a duro de oun   grin

E pari owe yi:

A ki i fi ika ro eti, k'afi ro imu,________________________________________

(E ma pe dahun o)  wink
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by kolaoloye(m): 7:56am On Dec 03, 2008
OLAADEGBU:

Arakunrin Kola, eti pe ju.

E pari owe yi:

A ki i fi ika ro eti, k'afi ro imu,________________________________________

(E ma pe dahun o)  wink

A ki i fi ika ro eti, k'afi ro imu- ika ti o ba to simu la'fi nromu.

Eni ti o ba mo'ju ogun (god of iron) ni a nje ki o pa obi ni're

E mase gbagbe pe ire ni ile ogun,eni ti o ba si mo oju re ni a nje ki o se nkan etutu regrin
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by kolaoloye(m): 7:59am On Dec 03, 2008
E gba eyi, ki e ye wo grin

Eni ti o ba fe sin oku iya re_______________________-
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by OLAADEGBU(m): 7:59pm On Dec 03, 2008
kola oloye:

A ki i fi ika ro eti, k'afi ro imu- ika ti o ba to simu la'fi nromu.

Itumo owe yen le so, e o pari re wink

A ki i fi ika ro eti, ki afi ro imu, ki awa tun fi ta eyin grin
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by OLAADEGBU(m): 8:01pm On Dec 03, 2008
kola oloye:

A ki i fi ika ro eti, k'afi ro imu- ika ti o ba to simu la'fi nromu.

Eni ti o ba mo'ju ogun (god of iron) ni a nje ki o pa obi ni're

E mase gbagbe pe ire ni ile ogun,eni ti o ba si mo oju re ni a nje ki o se nkan etutu regrin

E se pupo ti e ba wa pari owe t' onipon yen. cheesy
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by kolaoloye(m): 1:03pm On Dec 04, 2008
@Olaadegbu,
mo ma ngbadun yin bi oyinbo ti ma ngbadun siga cheesy
Eni ti o ba fe sin oku iya re____________________--
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by kolaoloye(m): 8:30am On Dec 12, 2008
Eni ti o ba fe sin oku iya re, ko gbodo duro ni'bi ti okere ti nse grin

O dara na, e gba omiran
Lagate-lagate, eniti egun ba gun_________________________
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by Godalone(m): 10:11am On Dec 12, 2008
Kolao loye epele mbe o
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by goodass(m): 8:53pm On Dec 12, 2008
kola oloye:

Eni ti o ba fe sin oku iya re, ko gbodo duro ni'bi ti okere ti nse grin

O dara na, e gba omiran
Lagate-lagate, eniti egun ba gun_________________________

nii sa to alabe lo
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by KollyJay(m): 9:04pm On Dec 12, 2008
Eyin temi omo oduduwa, ese pupo, mo n gbadun yin.


Take this.



Gbogbo aluwala ologbo, ,
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by kolaoloye(m): 8:25am On Dec 13, 2008
KollyJay:

Eyin temi omo oduduwa, ese pupo, mo n gbadun yin.
Take this.

Gbogbo aluwala ologbo, ,

Gbogbo aluwala ologbo,ko koja ati k'eran je grin
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by kolaoloye(m): 8:31am On Dec 13, 2008
E gba ki e ye wo
A kii ni'gi lagbala________________________-

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) ... (25) (Reply)

Lovely Pictures / Match 2 Personalities 2 Make A Couple / Who Are You Missing Today?

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 48
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.