Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,161,697 members, 7,847,821 topics. Date: Sunday, 02 June 2024 at 08:50 AM

Eku'le Ati E K'aabo - Culture - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / Eku'le Ati E K'aabo (3796 Views)

Join This Group Today: Lilo Ewe Ati Egbo Ati Eranko (herbs; The Magic Healer) / Lilo Ewe Ati Egbo Fun Iwosan, Itusile Ati Aseyori / LILO OGUN IBILE FUN ITOJU,IWOSAN ATI ASEYORI (2) (3) (4)

(1) (Reply) (Go Down)

Eku'le Ati E K'aabo by SisiGbeborun(f): 2:18pm On Jul 22, 2015
Ti e k'aabo ba je, welcome ni ede oyinbo, e jowo kini eku'le ni ede oyinbo?

Ta lo mo?
Re: Eku'le Ati E K'aabo by tpiadotcom: 2:20pm On Jul 22, 2015
ekule is I'm back.

Ni Yoruba, o maa je e ku isimi tabi mo ti de.


e ku itoju ile.
Re: Eku'le Ati E K'aabo by isan(m): 2:25pm On Jul 22, 2015
I'm back
Re: Eku'le Ati E K'aabo by Hero10001: 2:47pm On Jul 22, 2015
Eni ti ko ki eni ku'ile yio padanu ekaabo. I'm back, youre welcome.
Re: Eku'le Ati E K'aabo by Wealthyone: 2:51pm On Jul 22, 2015
Ekule is "Hello"

I'm back is Motide wink
Re: Eku'le Ati E K'aabo by scholes0(m): 5:02pm On Jul 22, 2015
"E ku Ile" ko ni itumo taara ni ede geesi tabi oyinbo.
Ikini yii wa lara abala ede Yoruba ti ko ni itumo pato ninu ede awon amunisin, nitori wipe asa ati ise wa, ati awon Oynbo yato si ara won. smiley
Nje alaye mi ye bi
Re: Eku'le Ati E K'aabo by tpiadotcom: 7:08pm On Jul 22, 2015
beeni

(1) (Reply)

Kudos To Gov. Isa Yuguda(Best Governor)! Bauchi pictures / Understanding The Meaning Of "Amen" And Why You Shouldn't Say "Amen" / Naija Street Hawker / Bus Conductor Slangs

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 5
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.