Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,162,739 members, 7,851,540 topics. Date: Wednesday, 05 June 2024 at 10:03 PM

Isese Lagba - Culture - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / Isese Lagba (8226 Views)

Isese Festival: Osun Declares Monday Public Holiday / 2017 Isese Festival At Igbogbo, Lagos (Photos) / 5 Facts About Isese Day As Yorubas Worldwide Celebrate Today (2) (3) (4)

(1) (Reply) (Go Down)

Isese Lagba by Adabaemi01: 4:21pm On Mar 31, 2016
Oduduwa a gbe gbogbo wa o
Re: Isese Lagba by iPopAlomo(m): 4:24pm On Mar 31, 2016
Isese la o ma sé ooo

Isese la o ma sé... grin
Re: Isese Lagba by Adabaemi01: 4:29pm On Mar 31, 2016
¤OFO ASEGBE TODAJU(pelu atare mesan)¤

Haa x3.
Gbogbo ota patapata to nperi mi igi daa.
Ki won peri mi si oran bukuru mo.
Igbagbe x3.
Igbagbe lose pepeye nio se ranti lase lorun.
Igbagbe x3.
Igbagbe lose Aja nio se ranti gbawo lorun.
Igbagbe x3.
Bi alatankun baji, aa wa igi tose lori kiri.
Igbagbe x3.
Idamu toba Alatankun nijosi to nfi ji to nwa igi to se lori kiri ko maa ba gbogbo eyin ota awa FANS egbe yi.
ASE!!!.

1 Like

Re: Isese Lagba by Adabaemi01: 4:32pm On Mar 31, 2016
AFORAN EJO TIWON O FI DA ENI TIWON BATI MO EWON SILE KIAKIA*
Schapp, ewe oriji, ao fi oti naa gbo, ao wa Ologbo ako nla kan, ao diimu, ao fi obe du lorun, ao waa da eje ologbo na si ohun ti agbona, ao lofun eni ti owa lewon[prisoner]naa ni gaasi kan mu, ko baaje odo olopa nii, ejo naa aa pare kiakia.
ODAJU OOO/!!!\

1 Like

Re: Isese Lagba by enigstil(m): 8:38pm On Apr 02, 2016
Isese lagba ni toto. Baba ekushe eledua ati awon to laye ama je ki oju yin se, ashe. Ejowo bawo ni eniyan se le ri yin?

(1) (Reply)

igbo Masquerades / What Is Eyo Festival All About? / ICSN Iri Ji (new Yam) Festival 2014

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 7
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.